Diutaronomi 27:7 BM

7 Ẹ rú ẹbọ alaafia, kí ẹ jẹ ẹ́ níbẹ̀, kí ẹ sì máa yọ̀ níwájú OLUWA Ọlọrun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 27

Wo Diutaronomi 27:7 ni o tọ