Diutaronomi 29:24 BM

24 gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ni yóo máa bèèrè pé, ‘Kí ló dé tí OLUWA fi sọ ilẹ̀ yìí dà báyìí? Kí ló dé tí ibinu ńlá OLUWA fi dé sórí ilẹ̀ yìí?’

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:24 ni o tọ