Diutaronomi 29:25 BM

25 Àwọn eniyan yóo sì máa dáhùn pé, ‘Nítorí pé wọn kò mú majẹmu OLUWA Ọlọrun ṣẹ, tí ó bá àwọn baba wọn dá nígbà tí ó kó wọn jáde ní ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Diutaronomi 29

Wo Diutaronomi 29:25 ni o tọ