Diutaronomi 32:7 BM

7 “Ẹ ranti ìgbà àtijọ́,ẹ ṣe akiyesi ọpọlọpọ ọdún tí ó ti kọjá.Ẹ bèèrè lọ́wọ́ baba yín, yóo fihàn yín,Ẹ bi àwọn àgbààgbà yín,wọn yóo sì sọ fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:7 ni o tọ