Diutaronomi 5:31 BM

31 Ṣugbọn ìwọ dúró tì mí níhìn-ín, n óo sì sọ gbogbo òfin ati ìlànà ati ìdájọ́ tí o óo kọ́ wọn, kí wọ́n lè máa pa wọ́n mọ́, ní ilẹ̀ tí n óo fún wọn.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:31 ni o tọ