Diutaronomi 5:32 BM

32 “Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra kí ẹ sì ṣe gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun yín pa láṣẹ fun yín; ẹ kò gbọdọ̀ ṣe àìgbọràn ninu ohunkohun.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:32 ni o tọ