Diutaronomi 6:20 BM

20 “Nígbà tí àwọn ọmọ yín bá bèèrè lọ́jọ́ iwájú pé, kí ni ìtumọ̀ àwọn ẹ̀rí ati ìlànà ati òfin tí OLUWA pa láṣẹ fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 6

Wo Diutaronomi 6:20 ni o tọ