Diutaronomi 8:6 BM

6 Nítorí náà, ẹ pa òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́, nípa rírìn ní ọ̀nà rẹ̀ ati bíbẹ̀rù rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:6 ni o tọ