Diutaronomi 8:7 BM

7 Nítorí pé ilẹ̀ dáradára ni ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín ń mu yín lọ. Ó kún fún ọpọlọpọ adágún omi, ati orísun omi tí ó ń tú jáde ninu àwọn àfonífojì ati lára àwọn òkè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:7 ni o tọ