Gẹn 1:16 YCE

16 Ọlọrun si dá imọlẹ nla meji; imọlẹ ti o tobi lati ṣe akoso ọsán, ati imọlẹ ti o kere lati ṣe akoso oru: o si dá awọn irawọ pẹlu.

Ka pipe ipin Gẹn 1

Wo Gẹn 1:16 ni o tọ