Gẹn 10:32 YCE

32 Wọnyi ni idile awọn ọmọ Noa, gẹgẹ bi iran wọn, li orilẹ-ède wọn: lati ọwọ́ awọn wọnyi wá li a ti pín orilẹ-ède aiye lẹhin kíkun-omi.

Ka pipe ipin Gẹn 10

Wo Gẹn 10:32 ni o tọ