Gẹn 10:5 YCE

5 Lati ọdọ awọn wọnyi li a ti pín erekuṣu awọn orilẹ-ède ni ilẹ wọn, olukuluku gẹgẹ bi ohùn rẹ̀; gẹgẹ bi idile wọn, li orilẹ-ède wọn.

Ka pipe ipin Gẹn 10

Wo Gẹn 10:5 ni o tọ