Gẹn 11:9 YCE

9 Nitorina li a ṣe npè orukọ ilu na ni Babeli; nitori ibẹ̀ li OLUWA gbe dà ède araiye rú, lati ibẹ̀ lọ OLUWA si tú wọn ká kiri si ori ilẹ gbogbo.

Ka pipe ipin Gẹn 11

Wo Gẹn 11:9 ni o tọ