Gẹn 12:17 YCE

17 OLUWA si fi iyọnu nla yọ Farao ati awọn ara ile rẹ̀ li ẹnu, nitori Sarai aya Abramu.

Ka pipe ipin Gẹn 12

Wo Gẹn 12:17 ni o tọ