Gẹn 15:17 YCE

17 O si ṣe nigbati õrùn wọ̀, òkunkun si ṣú, kiyesi i ileru elẽfin, ati iná fitila ti nkọja lãrin ẹ̀la wọnni.

Ka pipe ipin Gẹn 15

Wo Gẹn 15:17 ni o tọ