Gẹn 15:4 YCE

4 Si wo o, ọ̀rọ OLUWA tọ̀ ọ wá, wipe, Eleyi ki yio ṣe arole rẹ; bikoṣe ẹniti yio ti inu ara rẹ jade, on ni yio ṣe arole rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 15

Wo Gẹn 15:4 ni o tọ