Gẹn 16:15 YCE

15 Hagari si bí ọmọkunrin kan fun Abramu: Abramu si pè orukọ ọmọ ti Hagari bí ni Iṣmaeli.

Ka pipe ipin Gẹn 16

Wo Gẹn 16:15 ni o tọ