8 O si wipe, Hagari ọmọbinrin ọdọ Sarai, nibo ni iwọ ti mbọ̀? nibo ni iwọ si nrè? O si wipe, emi sá kuro niwaju Sarai oluwa mi.
Ka pipe ipin Gẹn 16
Wo Gẹn 16:8 ni o tọ