Gẹn 17:10 YCE

10 Eyi ni majẹmu mi, ti ẹnyin o ma pamọ́ lãrin temi ti nyin, ati lãrin irú-ọmọ rẹ, lẹhin rẹ; gbogbo ọmọkunrin inu nyin li a o kọ ni ilà.

Ka pipe ipin Gẹn 17

Wo Gẹn 17:10 ni o tọ