Gẹn 17:4 YCE

4 Bi o ṣe ti emi ni, kiyesi i, majẹmu mi wà pẹlu rẹ, iwọ o si ṣe baba orilẹ-ède pupọ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 17

Wo Gẹn 17:4 ni o tọ