Gẹn 18:26 YCE

26 OLUWA si wipe, Bi mo ba ri ãdọta olododo ninu ilu Sodomu, njẹ emi o dá gbogbo ibẹ̀ si nitori wọn.

Ka pipe ipin Gẹn 18

Wo Gẹn 18:26 ni o tọ