Gẹn 18:32 YCE

32 O si wipe, Jọ̃, ki inu ki o máṣe bi OLUWA, ẹ̃kanṣoṣo yi li emi o si wi mọ. Bọya a o ri mẹwa nibẹ̀. On si wipe, Emi ki yio run u nitori mẹwa.

Ka pipe ipin Gẹn 18

Wo Gẹn 18:32 ni o tọ