Gẹn 19:11 YCE

11 Nwọn si bù ifọju lù awọn ọkunrin ti o wà li ẹnu-ọ̀na ile na, ati ewe ati àgba: bẹ̃ni nwọn dá ara wọn li agara lati ri ẹnu-ọ̀na.

Ka pipe ipin Gẹn 19

Wo Gẹn 19:11 ni o tọ