Gẹn 22:1 YCE

1 O si ṣe lẹhin nkan wọnyi ni Ọlọrun dan Abrahamu wò, o si wi fun u pe, Abrahamu: on si dahùn pe, Emi niyi.

Ka pipe ipin Gẹn 22

Wo Gẹn 22:1 ni o tọ