Gẹn 23:11 YCE

11 Bẹ̃kọ, Oluwa mi, gbọ́ ti emi, mo fi oko na fun ọ, ati ihò ti o wà nibẹ̀, mo fi fun ọ: li oju awọn ọmọ awọn enia mi ni mo fi i fun ọ: sin okú rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 23

Wo Gẹn 23:11 ni o tọ