Gẹn 24:23 YCE

23 O si bi i pe, Ọmọbinrin tani iwọ iṣe? Emi bẹ̀ ọ, wi fun mi: àye wà ni ile baba rẹ fun wa lati wọ̀ si?

Ka pipe ipin Gẹn 24

Wo Gẹn 24:23 ni o tọ