Gẹn 24:29 YCE

29 Rebeka si li arakunrin kan, orukọ rẹ̀ si ni Labani: Labani si sure jade tọ̀ ọkunrin na lọ si ibi kanga.

Ka pipe ipin Gẹn 24

Wo Gẹn 24:29 ni o tọ