Gẹn 24:33 YCE

33 A si gbé onjẹ kalẹ fun u lati jẹ: ṣugbọn on si wipe, Emi ki yio jẹun titi emi o fi jiṣẹ mi tán. On si wipe, Ma wi.

Ka pipe ipin Gẹn 24

Wo Gẹn 24:33 ni o tọ