42 Emi si de si ibi kanga loni, mo si wipe, OLUWA, Ọlọrun Abrahamu oluwa mi, bi iwọ ba mu ọ̀na àjo mi ti mo nlọ nisisiyi dara:
Ka pipe ipin Gẹn 24
Wo Gẹn 24:42 ni o tọ