Gẹn 24:44 YCE

44 Ti o si wi fun mi pe, Iwọ mu, emi o si pọn fun awọn ibakasiẹ rẹ pẹlu: ki on na ki o ṣe obinrin ti OLUWA ti yàn fun ọmọ oluwa mi.

Ka pipe ipin Gẹn 24

Wo Gẹn 24:44 ni o tọ