Gẹn 25:20 YCE

20 Isaaki si jẹ ẹni ogoji ọdún, nigbati o mu Rebeka, ọmọbinrin Betueli, ara Siria ti Padan-aramu, arabinrin Labani ara Siria, li aya.

Ka pipe ipin Gẹn 25

Wo Gẹn 25:20 ni o tọ