Gẹn 26:1 YCE

1 ÌYAN kan si mu ni ilẹ na, lẹhin ìyan ti o tetekọ mu li ọjọ́ Abrahamu. Isaaki si tọ̀ Abimeleki, ọba awọn ara Filistia lọ, si Gerari.

Ka pipe ipin Gẹn 26

Wo Gẹn 26:1 ni o tọ