Gẹn 26:15 YCE

15 Nitori gbogbo kanga ti awọn ọmọ-ọdọ baba rẹ̀ ti wà li ọjọ́ Abrahamu, baba rẹ̀, awọn ara Filistia dí wọn, nwọn si fi erupẹ dí wọn.

Ka pipe ipin Gẹn 26

Wo Gẹn 26:15 ni o tọ