Gẹn 26:26 YCE

26 Nigbana li Abimeleki tọ̀ ọ lati Gerari lọ, ati Ahusati, ọkan ninu awọn ọ̀rẹ́ rẹ̀, ati Fikoli, olori ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 26

Wo Gẹn 26:26 ni o tọ