Gẹn 26:31 YCE

31 Nwọn si dide ni kutukutu owurọ̀, nwọn si bura fun ara wọn: Isaaki si rán wọn pada lọ, nwọn si lọ kuro lọdọ rẹ̀ li alafia.

Ka pipe ipin Gẹn 26

Wo Gẹn 26:31 ni o tọ