Gẹn 27:27 YCE

27 O si sunmọ ọ, o si fi ẹnu kò o li ẹnu: o si gbọ́ õrùn aṣọ rẹ̀, o si sure fun u, o si wipe, Wò o, õrùn ọmọ mi o dabi õrùn oko eyiti OLUWA ti busi.

Ka pipe ipin Gẹn 27

Wo Gẹn 27:27 ni o tọ