Gẹn 27:40 YCE

40 Nipa idà rẹ ni iwọ o ma gbé, iwọ o si ma sìn arakunrin rẹ; yio si ṣe nigbati iwọ ba di alagbara tan, iwọ o já àjaga rẹ̀ kuro li ọrùn rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 27

Wo Gẹn 27:40 ni o tọ