Gẹn 28:4 YCE

4 Ki o si fi ibukún Abrahamu fun ọ, fun iwọ ati fun irú-ọmọ rẹ pẹlu rẹ; ki iwọ ki o le ni ilẹ na ninu eyiti iwọ nṣe atipo, ti Ọlọrun fi fun Abrahamu.

Ka pipe ipin Gẹn 28

Wo Gẹn 28:4 ni o tọ