Gẹn 29:33 YCE

33 O si tun yún, o si bí ọmọkunrin kan; o si wipe, Nitori ti OLUWA ti gbọ́ pe a korira mi, nitorina li o ṣe fun mi li ọmọ yi pẹlu: o si sọ orukọ rẹ̀ ni Simeoni.

Ka pipe ipin Gẹn 29

Wo Gẹn 29:33 ni o tọ