Gẹn 3:24 YCE

24 Bẹ̃li o lé ọkunrin na jade; o si fi awọn kerubu ati idà ina dè ìha ìla-õrùn Edeni ti njù kakiri, lati ma ṣọ́ ọ̀na igi ìye na.

Ka pipe ipin Gẹn 3

Wo Gẹn 3:24 ni o tọ