Gẹn 31:12 YCE

12 O si wipe, Gbé oju rẹ soke nisisiyi, ki o si wò, gbogbo awọn obukọ ti ngùn awọn ẹran li o ṣe tototó, abilà, ati alamì: nitori ti emi ti ri ohun gbogbo ti Labani nṣe si ọ.

Ka pipe ipin Gẹn 31

Wo Gẹn 31:12 ni o tọ