Gẹn 31:27 YCE

27 Ẽṣe ti iwọ fi salọ li aṣíri, ti iwọ si tàn mi jẹ; ti iwọ kò si wi fun mi ki emi ki o le fi ayọ̀ ati orin, ati ìlu, ati dùru, sìn ọ;

Ka pipe ipin Gẹn 31

Wo Gẹn 31:27 ni o tọ