Gẹn 32:11 YCE

11 Emi bẹ̀ ọ, gbà mi lọwọ arakunrin mi, lọwọ Esau: nitori ti mo bẹ̀ru rẹ̀, ki o má ba wá lati kọlù mi, ti iya ti ọmọ.

Ka pipe ipin Gẹn 32

Wo Gẹn 32:11 ni o tọ