Gẹn 33:18 YCE

18 Jakobu si wá li alafia, si ilu Ṣekemu ti o wà ni ilẹ Kenaani, nigbati o ti Padan-aramu dé: o si pa agọ́ rẹ̀ niwaju ilu na.

Ka pipe ipin Gẹn 33

Wo Gẹn 33:18 ni o tọ