Gẹn 33:7 YCE

7 Ati Lea pẹlu ti on ti awọn ọmọ rẹ̀ sunmọ ọdọ rẹ̀, nwọn si tẹriba: nikẹhin ni Josefu ati Rakeli si sunmọ ọdọ rẹ̀, nwọn si tẹriba.

Ka pipe ipin Gẹn 33

Wo Gẹn 33:7 ni o tọ