16 Nigbana li awa o fi awọn ọmọbinrin wa fun nyin, awa o si mú awọn ọmọbinrin nyin sọdọ wa; awa o si ma bá nyin gbé, awa o si di enia kanna.
Ka pipe ipin Gẹn 34
Wo Gẹn 34:16 ni o tọ