Gẹn 34:22 YCE

22 Kìki ninu eyi li awọn ọkunrin na o ṣe jẹ fun wa, lati ma bá wa gbé, lati di enia kan, bi gbogbo ọkunrin inu wa ba kọlà, gẹgẹ bi nwọn ti kọlà.

Ka pipe ipin Gẹn 34

Wo Gẹn 34:22 ni o tọ