Gẹn 35:17 YCE

17 O si ṣe nigbati o wà ninu irọbí, ni iyãgba wi fun u pe, Máṣe bẹ̀ru: iwọ o si li ọmọkunrin yi pẹlu.

Ka pipe ipin Gẹn 35

Wo Gẹn 35:17 ni o tọ