Gẹn 35:29 YCE

29 Isaaki si jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ, o si kú, a si kó o jọ pẹlu awọn enia rẹ̀, o gbó, o si kún fun ọjọ́, awọn ọmọ rẹ̀, Esau ati Jakobu si sin i.

Ka pipe ipin Gẹn 35

Wo Gẹn 35:29 ni o tọ