Gẹn 36:43 YCE

43 Magdieli olori, Iramu olori: wọnyi li awọn olori Edomu, nipa itẹ̀dó wọn ni ilẹ iní wọn: eyi ni Esau, baba awọn ara Edomu.

Ka pipe ipin Gẹn 36

Wo Gẹn 36:43 ni o tọ